A trip to jamaica

 

A Trip to Jamaica
Fáìlì:A Trip to Jamaica poster.jpg
Theatrical release poster
AdaríRobert Peters
Olùgbékalẹ̀Ayo Makun
Àwọn òṣèré
Ilé-iṣẹ́ fíìmùCorporate World Pictures
OlùpínFilmOne
Déètì àgbéjáde
  • 25 Oṣù Kẹ̀sán 2016 (2016-09-25)
Àkókò100 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria

Ìrìn-àjò kan sí Ìlú Jàmáíkà jẹ́ erẹ́ oníṣe àgbéléwò aláwàdà Nàìjíríà ti ọdún 2016 tí Robert Peters ṣe olùdarí pẹ́lú Ayọ̀ Mákùn, Fúnkẹ́ Akindélé, Nse Ikpe Etim àti Dan Davies . ẹrẹ́ oníṣe àgbéléwò náà sọ ìtàn nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ sáwọn tọkọtaya kan tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣègbéyàwó ní ilé àwọn mọ̀lẹ́bí wọn lẹ́yìn odi ilẹ̀ Nàìjíríà, àti bí àṣírí ẹni tó gbà wọ́n ṣe mú kí ìgbéyàwó wọn túká pẹ̀lú ìpayà àṣà ìṣẹ̀dálẹ̀ orílẹ̀-èdè tuntun náà, tí wọ́n sì ń gbé pẹ̀lú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè tó gbajúmọ̀..Tilẹ aseyori ńlá, tí ó ta yọ àṣesílẹ̀ tí 30 Days in Atlanta fi ẹsẹ́ lé fun awọn erẹ́ oníṣe àgbéléwò ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó gba oríyìn , ó ti gba orísirísi àgbéyẹ̀wò láti alárìíwísí.

Erẹ́ oníṣe àgbéléwò náà jẹ́ síṣe àfihàn àgbáyé ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣu Kẹsan Ọdún 2016 ní Ìpínlẹ̀ Èkó . Àfihàn náà jẹ́ ṣíṣe pẹ̀lú a gbá bọọlu aláfẹsẹ̀gbá olókìkí atijọ, bii Kanu Nwankwo, Jay Jay Okocha, Peter Rufai, Joseph Yobo àti Stephen Appiah .


From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Nelliwinne