Abayomi Gabriel Olonisakin | |
---|---|
![]() Ọ̀gá Ọmọṣẹ́ Ológun, Ọ̀gágun AG Olonisakin | |
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga July 2015 | |
Asíwájú | ACM. A.S Badeh |
Commander, Training and Doctrine Command (TRADOC) Nigerian Army | |
In office September 2013 – July 2015 | |
Asíwájú | Maj-Gen. S.Z. Uba |
Commander, Nigerian Army Corps of Signals | |
In office January 2013 – September 2013 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kejìlá 1961[1] Ekiti state, Nigeria |
Alma mater | Nigeria Military School Nigerian Defence Academy Obafemi Awolowo University |
Military service | |
Allegiance | ![]() |
Branch/service | ![]() |
Years of service | 1979 - |
Rank | General |
Commands | Chief of Defence Staff Commander, Training and Doctrine Command (TRADOC), Nigerian Army Commander, Nigerian Army Corps of Signals |
Abayomi Gabriel Olonisakin jẹ́ ọ̀gágun ní ilé-iṣẹ́ Jagunjagun orí-ilẹ̀ Nàìjíríà. Lọ́wọ́lọ́wọ́ Ọ̀gágun Olonisakin ni Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari ló yàn sípò yìí ní ojọ́ 13 Osù Keje 2015.[2]