Akínwùnmí Aḿbọ̀dé (tí a bí ní Ọ̣jọ́ Kẹrìnlá Oṣù Kẹfà Ọdún 1963) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ gómìnà Ìpínlẹ̀ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó láàrin ọdún 2015 sí 2019.[1] Ó ti fìgbà kan jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n. Ó jẹ́ Olùgbaninímọ̀ràn lórí ìsúnná owó kí ó tó wá díje dupò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2015.
Akínwùnmí Aḿbọ̀dé | |
---|---|
14th Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó | |
In office 29 May 2015 – 29 May 2019 | |
Deputy | Idiat Adebule |
Asíwájú | Babatunde Fashola |
Arọ́pò | Babajide Sanwo-Olu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹfà 1963 |