Bayo Adebowale |
---|
Bayo Adebowale (bí ni ọjọ́ kẹfà, Oṣù Òkudù, ọdún 1944), jẹ́ òǹkọ̀wé àròsọ, akéwì, Ọ̀jọ̀gbọ́n, lámèyító, alákòóso ìyára ìsọlọ́jọ ìwé àti ìkàwé àti olùdásílẹ̀ Ibùdó àṣà àti ìyára ìsọlọ́jọ̀ ìwé àti ìkàwé Àjogúnbá Adúláwò (African Heritage Library and Cultural Centre) ní Adéyípo, Ìbàdàn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.