Beverly Naya | |
---|---|
![]() Naya on NdaniTV in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Beverly Ifunaya Bassey 17 Oṣù Kẹrin 1989 London, England, United Kingdom |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008–present |
Beverly Naya (tí àbísọ rẹ̀ jẹ́ Beverly Ifunaya Bassey; tí wọ́n bí ní 17 Oṣù Kẹẹ̀rin Ọdún 1989) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti òṣèré tí ó ní ìlérí jùlọ níbi ayẹyẹ Best of Nollywood Awards ti ọdún 2010. Ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó yára tayọ jùlọ níbi ayẹyẹ City People Entertainment Awards ti ọdún 2011.[1][2][3]