Blossom Chukwujekwu | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kọkànlá 1983 Benin City, Edo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Benson Idahosa University |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009-present |
Gbajúmọ̀ fún |
|
Olólùfẹ́ | Ehinome (nee Akhuemokhan) Chukwujekwu |
Blossom Chukwujekwu jẹ́ òṣèré láti orílé èdè Nàìjíríà , tí ó ṣe akọṣere rẹ̀ ní ọdún 2009. Ní ọdún 2015, ó gba Àmì -ẹye Òṣeré àtìlẹyìn tí ó dára jù lọ ní Africa Magic Viewers Choice Awards. [1]