David Uzochukwu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | David Ejikeme Uzochukwu 10 Oṣù Kejìlá 1998 Innsbruck, Austria |
Orílẹ̀-èdè | Austrian–Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Austrian–Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Humboldt-Universität zu Berlin |
Gbajúmọ̀ fún | Fọ́tòyíyà |
Awards | EyeEm, Flickr's 20 Under 20 |
Website | Official website |
David Ejikeme Uzochukwu (tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù Kejìlá ọdún 1998) jẹ́ olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Austria àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bákannáà ẹni tí ó jẹ́ wípé àwòrán fọ́tòyíyà ni ó dojú kọ jùlọ. Brussels àti Berlin ni Uzochukwu ń gbé. Ó jẹ́ ókan lára àwọn queer.[1]