Desmond Elliot

Desmond Elliot

Desmond Oluwashola Elliot (ti a bi ojo keerin Osu keji odun 1974) jẹ oludari fiimu Naijiria, ati oloselu . [1] [2] Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí aṣòfin ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó, eeka ti Surulere, ní Ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹrin ọdún 2015 nínú Ìdìbò Gbogbogbòò ní Nàìjíríà . Elliot ti njijadu lati di aṣoju fun ise Ojuu ti Ireti , “ise ti ko lere, ti kii ṣe ti ẹsin, ti kii ṣe ti iṣelu ti won ṣeto lati fun awọn alainireti ni ireti”, ninu eyiti yoo ṣiṣẹ lati ṣe atunṣe “aimọwe ọmọ ni Nàìjíríà àti Áfíríkà lápapọ̀” iyen toba jawe olu bori. O gba ami eye oṣere ti o ṣe atilẹyin julọ julọ ni ere-idaraya kan ni 2nd Africa Magic Viewers Choice Awards ati pe won yan fun oṣere ti o ṣe atilẹyin julọ ni ayeye kewa Africa Movie Academy Awards .

  1. . Lagos, Nigeria.  Missing or empty |title= (help);
  2. "Desmond Elliot for Face of Hope". Lagos, Nigeria. http://allafrica.com/stories/201002190902.html. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Nelliwinne