Edikang ikong jẹ́ ọbẹ̀ ẹ̀fọ́ tí ó ṣẹ̀ wá láti àárín àwọn èyà Efik ti Ìpínlẹ̀ Cross River, àwọn èèyàn Ibibio ti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní apá Gúúsù mọ́ ilẹ̀ Gúúsù ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2][3][4] Wọ́n gbà pé oúnjẹ aládìídùn ni delicacy láàárín àwọn èèyàn Nàìjíríà kan, ó sì máa ń di ṣíṣè lásìkò ayẹyẹ tí ó ṣe pàtàkì.[5][6] Edikang ikong jẹ́ ọbẹ̀ asaralóooore tí ó sì wọ́n púpọ̀ láti sè, ó sì ti di ṣíṣe àpèjúwe pé àwọn olówó nìkan ni ó sábàá máa ń jẹ ẹ́ ní Nàìjíríà.[5] Ohun èlò tí wọ́n ń lò fún edikang ikong ni ògúnfe àti ẹja gbígbẹ, ẹran ìgbẹ́,edé, shaki, Kanda, ewé, gbúre, ugu, àlùbọ́sà, periwinkle, epo pupa, iyọ̀ àti ata.[1][5][7][8][9]
Lẹ́yìn ṣíṣè, edikang ikong sábàá máa ń di jíjẹ pẹ̀lú fufu, wheat flour, eba, tàbí iyán.[10]
<ref>
tag; no text was provided for refs named Pulse 20152
<ref>
tag; no text was provided for refs named Ukpong 20162
<ref>
tag; no text was provided for refs named Iyobebe 20162
<ref>
tag; no text was provided for refs named Agbenson 20142
<ref>
tag; no text was provided for refs named Inyese 20152