Eve Esin | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Evelyn Esin 17 Oṣù Kẹ̀wá 1981 Akwa Ibom State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Calabar |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008-Present |
Eve Esin jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards fún ẹ̀ka ti Òṣèrébìnrin tó ní ìlérí jùlọ ni Nàìjíríà ní ọdún 2015, àmì-ẹ̀yẹ ti AMAA fún amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ àti àmì-ẹ̀yẹ AMVCA fún ti òṣèrébìnrin tó dára jùlọ nínu eré ìtàgé.[1][2][3]