Femi Branch

Femi Branch
Ọjọ́ìbíDavid Babafemi Mauton Osunkoya
(1970-05-14)14 Oṣù Kàrún 1970
Sagamu, Ogun, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • actor
  • playwright
  • poet
  • filmmaker
  • producer
  • director
  • model
  • dramatist
Ìgbà iṣẹ́1991–present
Gbajúmọ̀ fúnAuthor of 409 page Anthology of Fifty Poems and Three Plays titled FROM SENBORA published in Dec. 2010 Producer/Writer of the Movie AWAY FROM HOME (2005)
Notable workFROM SENBORA - an Anthology of Fifty Poems and Three Plays
Ọmọ ìlúOdosenbora
Àwọn ọmọTwo
Parent(s)Ọ̀túba Gbolade & Chief Mrs Modúpẹ́ Ọ̀ṣúnkọ̀yà
Àwọn olùbátanBarr. Olugboyega Osunkoya, Apostle John Benhotons
AwardsSpecial Recognition Award, Ambassadors O. A. U. Ile Ife, Actor of the Year, Moshood Abiola Polytechnic, Ogun State, Special Recognition Award, University of Illorin, African Youth Council Special Recognition.
Websitewww.femibranch.com

Fẹ́mi Babáfẹ́mi Branch ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Karùn ún, ọdún 1970 (14-5-1970). Jẹ́ òṣèré Orí-ìtàgé, Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì,olùkọ̀tàn àti akọ ewì àpilẹ̀kọ , adarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1][2]

  1. "TOP ACTOR FEMI BRANCH OPENS UP ON N4M DEBT SCANDAL". nigeriafilms.com. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015. 
  2. "Nollywood Actor, Femi Branch Play Host @ Miss Insurance Grand Finale -- article". dailytimes.com.ng. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Nelliwinne