JJ Bunny |
---|
Ọjọ́ìbí | JOY ORIE NIGERIA |
---|
Iṣẹ́ | Actress, recording artist, record producer, screenwriter |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 2009–14 |
---|
Website | www.jjbunny.com |
---|
JJ Bunny jẹ́ òṣèébìnrin ilẹ̀ America tẹ́lẹ̀ rí[1][2][3] tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè America. O máa ń gbohùn sílẹ̀[4], ó sì tún jẹ́ aṣàgbéjáde fíìmù, tí ó ní àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ nínú fíìmù[5][6] "Caged"[7], ní ọdún 2009.[8][9] Ó ti kúrò nínú ẹgbẹ́ fíìmù Nollywood, ó sì ti ń ṣe fíìmù Gollywood báyìí.
- ↑ Ghanamma.com. "Listed as Nollywood A-lister". Retrieved June 27, 2012.
- ↑ Nollywooduncut.com. "JJ Bunny in Nollywood USA Films". Archived from the original on March 22, 2011. Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Africanevents.com. "JJ Bunny Receives Awards". Archived from the original on July 22, 2012. Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Discogs.com. "Album Release page". Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Trendy Africa. "JJ Bunny Co-Director, actress". Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Modernghana.com. "JJ Bunny makes impact in USA for Nollywood". Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Trendy Africa. "Caged". Archived from the original on February 21, 2010. Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Golden Icons. "JJ Bunny's is a Exe. Prod., producer". Archived from the original on July 11, 2011. Retrieved March 9, 2011.
- ↑ Movies.fienipa.com. "JJ Bunny History". Retrieved March 9, 2011.