Juliana Olayode | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Juliana Olúwatóbilọ́ba Olóyèdé 7 Oṣù Kẹfà 1995 Èkó , Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Toyo Baby |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnri , Oǹkọ̀wé, Asọ̀rọ̀móríyá |
Ìgbà iṣẹ́ | Ọdún 2015 títí di òní yìí |
Juliana Olúwatóbilọ́ba Ọláyọdé, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Toyo Baby, nípa ipa tí ó kó nínú eré Jenifa's Diary gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀dá-ìtàn, Tóyọ̀sí jẹ́ Òṣèrébìnri sinimá àgbéléwò àti ti tẹlifíṣàn, ó tún jẹ́ aṣègbè fún ìbálòpọ̀-ẹ̀tọ́ ọmọ Nàìjíríà.[1][2][3] Ó tún jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká nípa àtakò rẹ̀ sí ìbálòpọ̀ lọ́kọláya láìṣe ìgbéyàwó tó wọ́pọ̀ láàárín àwọn ọ̀dọ́.[4]