Kunle Remi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Òyekúnlé Ọpẹ́yẹmí Ọlúwarẹ̀mí 18 Oṣù Kẹ̀wá 1988 Gboko, Benue, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Kunle Rhemmy Teslim Terdo KR |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Fáṣítì Ìbàdàn New York Film Academy |
Iṣẹ́ | Ọ̀ṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010 – Present |
Kúnlé Rẹ̀mí (Wọ́n bi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹwàá, ọdún 1988 | Orúkọ ìbí- Oyèkúnlé Ọpẹ́yẹmí Olúwarẹ̀mí) jẹ́ Òṣèré Nàìjíríà , tí wọ́n mọ̀ ọ́ fún àwọn ipa ribiribi rẹ̀ ní Falling,[1] Family ForeverÀdàkọ:Cn and Tinsel. Ó di olókìkí lẹ́hìn ìgbà tí ó borí ìgbà kéjẹ tí wọ́n ṣe Gulder Ultimate Search ní ọdún 2010.[2] Ó parí láti New York Film Academy.[3]