Michelle Obama | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kínní 1964 Chicago, Illinois |
Ibùgbé | Chicago, Illinois |
Orílẹ̀-èdè | American |
Ẹ̀kọ́ | A.B.[1],in sociology, cum laude; J.D. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Princeton University, Harvard Law School |
Iṣẹ́ | Lawyer |
Àwọn ọmọ | Malia Ann and Sasha |
Parent(s) | Frasier Robinson and Marian Robinson |
Michelle LaVaughn Robinson Obama (ọjọ́-ìbí 17 January, 1964) jẹ́ aláwọ̀dúdú ọmọ ilẹ̀ Amerika; agbẹjọ́rò ni, òhun sì ni ìyàwó Barack Obama to je Aare ile Amẹ́ríkà.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |