Ngozi Nwosu |
---|
 |
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kẹjọ 1963 (1963-08-01) (ọmọ ọdún 61) ìlú Èkó |
---|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
---|
Iṣẹ́ | Actress |
---|
Gbajúmọ̀ fún | Ripples Living in Bondage Fuji House of Commotion |
---|
Wọ́n bí Ngozi Nwosu ní Ọjọ́ Kínní, Oṣù Kẹẹ̀jọ Ọdún 1963. Ó jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe rẹ̀ pẹ̀lú ṣíṣe eré èdè Yorùbá ṣááju kí ó tó wá kópa nínu eré èdè ígbò kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Living in Bondage.[3][4][5]
- ↑ Adebayo, Tireni (March 11, 2022). ""God healed me when they thought it was over" Ngozi Nwosu comforts Kemi Afolabi - Kemi Filani News". Kemi Filani News. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ Kenechi, Stephen (January 23, 2022). "'It felt like being buried alive' - Ngozi Nwosu recalls rumours on health struggle". TheCable Lifestyle. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ "My regrets about my marriage, Ngozi Nwosu speaks".
- ↑ "I’ll get married at the right time – 53-year-old actress, Ngozi Nwosu".
- ↑ Ogala, George (June 6, 2020). "INTERVIEW: Why I don't believe in prophets - Ngozi Nwosu". Premium Times Nigeria. Retrieved May 24, 2022.