Noo Saro-Wiwa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | British-Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | British, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Columbia University |
Iṣẹ́ | Writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2012 - present |
Gbajúmọ̀ fún | Travel writing |
Notable work | Transwonderland: Travel in Nigeria |
Àwọn olùbátan |
|
Noo Saro-Wiwa jẹ́ ònkọ̀we ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí sí ìlú Britain. Ó jẹ́ ọmọ bíbí inú Ken Saro-Wiwa..