Oladipo Diya | |
---|---|
9th Chief of General Staff | |
In office 1993–1997 | |
Ààrẹ | Gen. Sani Abacha gegebi Olori Orile-ede |
Asíwájú | Adm. Augustus Aikhomu |
Arọ́pò | Adm. Mike Akhigbe |
Chief of Defence Staff | |
In office 1993–1993 | |
Asíwájú | Gen. Sani Abacha |
Arọ́pò | Gen. Abdulsalami Abubakar |
Governor of Ogun State | |
In office January 1984 – August 1985 | |
Asíwájú | Olabisi Onabanjo |
Arọ́pò | Oladayo Popoola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kẹrin 1944 Odogbolu, Ogun State, Nigeria |
Alma mater | Nigerian Defence Academy |
Military service | |
Allegiance | ![]() |
Branch/service | Nigerian Army |
Years of service | 1964-1997 |
Rank | Lieutenant General |
Donaldson Oladipo Diya (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣu kẹrin, odún 1994 - 26 Oṣù Kẹta 2023) jẹ́ ajagun gbogboogbò ti orílẹ̀-èdè Naijiria tí ó sì ti fìgbà kan jẹ́ oloyè àwọn ajagun ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì tún jẹ́ igba-keji aare ti Nàìjíríà lábẹ́ ìjọba ológun ti olórí ìlú Sani Abacha láti ọdún 1994 títí tí wọ́n fi fi ẹ̀sùn ọ̀tẹ̀ kàn án ní ọdún 1997.[1] Ó fìgbà kan jẹ́ oloye akogun àti gómìnà ológun ti Ogun State láti oṣu kìíní, ọdún 1984 títí di oṣu kẹjọ ọdún 1985.
|url-status=
ignored (help)