Ologun Kutere | |
---|---|
Oba Èkó | |
c. 1780 - 1806 | |
Eletu Kekere | |
Adele Ajosun | |
Issue | |
Eshinlokun, Adele Ajosun, Akiolu, Olukoya, Olusi and Akitoye. | |
[[Royal house|]] | Ado, Ologun Kutere |
Father | Alaagba |
Mother | Erelu Kuti |
Born | Lagos |
Died | c. 1803 Lagos |
Religion | Ifá |
Ologun Kutere jẹ gẹ́gẹ́ bi Oba Èkó láti 1780s títí di ọdún 1803.[1] Òun ló jẹ́ lẹ́yìn Oba Eletu Kekere, ẹni tí ó wà lórí oyè láti ọdún sí 1775 and 1780.
Ologun Kutere jẹ́ ọmọ Erelu Kuti, ẹni tí ó jé ọmọ Oba Ado, àti Alaagba ('Alagbigba'), ẹni tí ó jẹ́ ọmọ Ìjẹ̀sà àti olùbádámọ̀ràn Oba Akinsemoyin.[2]