Paul Igwe | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kọkànlá 1977 Ìpínlẹ̀ Èkó, |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Olùgbéré-jáde |
Ìgbà iṣẹ́ | 1998–present |
Website | whitestonetv.com/ |
Paul Igwe Wọ́n bí Paul Igwe ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù Kọkànlá ọdún 1977. Òun ni olùdásílẹ̀ "Whitestine Cinema". Ó jẹ́ olùgbéré-jáde, ònkọ̀wé, àti ẹni tí ó gba amì-ẹ̀yẹ fún dídarí ètò orí ẹrọ amóhù-máwòrán, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ó ni eré ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí àkólé rẹ̀ ń jẹ́ Clinic Matters, The Bemjamins, Ojays àti Asunder" tí ó sì darí àwọn eré náà.[1]