Shehu Musa Yar'Adua

Shehu Musa Yar'Adua

Shehu Musa Yar'Adua (March 5, 1943 – December 8, 1997) je omo orile-ede Naijiria to je onisowo, jagunjagun ati oloselu. Nigba ijoba ologun Ogagun Olusegun Obasanjo, Yar'Adua ni o je igbakeji olori orile-ede gege bi Oga Gbogbo Omose Ologun[1]. Yar'Adua ku ni ogba ewon ni ojo 8 osu 12, 1997 leyin atimole re lowo ijoba ologun Ogagun Sani Abacha nitori akitiyan re fun ijoba arailu.

Shehu Musa Yar'Adua ni egbon Aare Naijiria tele Umaru Yar'Adua.

  1. Biography of Sheu Musa Yar'Adua [1]

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Nelliwinne