Sola Asedeko | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ipinle Eko, Naijiria |
Orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2006 - lowolowo |
Gbajúmọ̀ fún | Abeni The Narrow Path |
Ṣọlá Asedeko jẹ́ òṣèré fiimu tí Ìlu Nàìjíríà, àti olùdarí. Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi Àbẹ̀ní fún ipa asíwáju rẹ̀ nínu Àbẹ̀ní, fiimu Nàìjíríà kan ti ọdún 2006, tí Túndé Kèlání ṣe ìtọ́sọ́nà rẹ̀.[1][2]