Surulere | |
---|---|
![]() Ibi t́ ó wà ní Ìlú Èkó | |
Orílẹ̀ èdè | ![]() |
Ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà | Ìpínlẹ̀ Èkó |
Area | |
• Total | 23 km2 (9 sq mi) |
Population | |
• Total | 503,975 |
• Density | 22,000/km2 (57,000/sq mi) |
Time zone | UTC+1 (CET) |
Surulere jẹ́ ibùgbé àti ibi iṣòwò agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ tó wà ní òke-odò ní Ìlú Èkó ní ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, agbègbè yíi tó ìwọn 23 km². ìkànìyàn tí wọ́n ṣe ní ọdún 2006 fihàn wípé ó kéré jù ènìyàn 503,975 ń gbé agbègbè yìi pẹ̀lú ìṣúpọ̀ olùgbé bíi 21,864 fún ìdá kan km².