Temmie Ovwasa tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlógúnọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1996 ni gbogbo ènìyàn mọ́ sí YBNL princess,[1] ni ó jẹ́ olórin , olùkọrin, àti òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì ń akọrin pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ agbórin-jáde YBNL Nation nígbà tí ó fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú wọn ní inú oṣù kẹjọ ọdún 2015[2] amọ́ tí ó kúrò ní ilé-iṣẹ́ náà ní inú ọdún 2020 lẹ́yìn tí èdè oun ati Olamide tí ó ni ilé-iṣẹ́ náà kò fẹ́ jọra mọ́.[3][4] Ovwasa ni ó fi hàn fáyé wípé obìnrin bí ẹgbẹ́ oun ni òun nífẹ́ sí láti ma bá ṣe àṣepọ̀.[5][6] Nígbà tí ó di ọdún 2020, ó gbé orin rẹ̀ akọ́kọ́ irú rẹ̀ tí ó ke nípa bí ọkùnrin ṣe ń ní àṣepọ̀ pẹ́lú ọkùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, èyí tí yóò mú kí ó jẹ́ irúfẹ́ rẹ̀ akọ́kọ́ irú rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[7]
Temmie Ovwasa |
---|
Ọjọ́ìbí | Temmie Ovwasa 29 Oṣù Kọkànlá 1996 (1996-11-29) (ọmọ ọdún 28) Ilorin, Ìpínlẹ̀ Kwara |
---|
Iṣẹ́ | |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 2016 - present |
---|
Musical career |
Irú orin | |
---|
Instruments | Vocals, Guiltar |
---|
Associated acts | Fireboydml |
---|
|
- ↑ "YBNL Princess Accuses Olamide Of Limiting Her Growth In The Music Industry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Archived from the original on 2021-02-17. Retrieved 2021-06-28.
- ↑ "How Olamide destroyed my career for 5 years – Temmie Ovwasa". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Retrieved 2021-06-28.
- ↑ "YBNL Princess Accuses Olamide Of Limiting Her Growth In The Music Industry". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-07. Archived from the original on 2021-02-17. Retrieved 2021-06-28.
- ↑ Oladimeji (2020-12-04). "YBNL Princess Reveals Why She Refused To Change Name Despite Leaving Olamide’s Label | 36NG" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28.
- ↑ "I Found Out That I'm A Lesbian At 5 –Temmie Onwasa - New National Star" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28.
- ↑ Olowolagba, Fikayo (2021-03-13). "I’m disgusted by heterosexuality - Temmie Ovwasa". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28.
- ↑ "Temmie Ovwasa dropped Nigeria's first-ever openly gay album, and it is amazing!". The Rustin Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-28. Retrieved 2021-06-07.