The Mercy of the Jungle (Faranse: La Miséricorde de la Jungle ) jẹ fiimu 2018 tagbaye ta ṣe agbejade lati ọdọ oludari Rwandan. O sọ itan ti awọn ọmọ-ogun Rwandan meji ti o yapa kuro ninu ẹgbẹ ologun wọn ni ibẹrẹ Ogun Kongo Keji ati Ijakadi wọn lati yege ninu agbegbe igbo ti o gbona jojo laaarin ija ologun lile. Fiimu na gba ami eye ti eleye Goolu ni FESPACO[1]