The Narrow Path

The Narrow Path
[[File:Fáìlì:Movie poster for The Narrow Path.jpg|200px|alt=]]
AdaríTúndé Kèlání
Òǹkọ̀wéTúndé Kèlání
Niji Akanni
Àwọn òṣèréSola Asedeko
Ayo Badmus
Khabirat Kafidipe
OrinBeautiful Nubia
Seun Owoaje
Ìyàwòrán sinimáLukaan Abdulrahman
Tunde Kelani
OlóòtúMumin Wale Kelani
Frank Efe Patrick
Ilé-iṣẹ́ fíìmùMainframe Film and Television Productions
OlùpínMainframe Film and Television Productions
Déètì àgbéjáde2006
Àkókò95 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish and Yoruba

The Narrow Path Ni eré oníṣẹ́ tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006, tí alàgbà Túndé Kèlání gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe àfàyọ eré yí láti inú ìwé onítàn The Virgin, ìwé tí Bayo Adebowale ke jáde.[2][3][4]

  1. Ekenyerengozi, Michael Chima (2013). NOLLYWOOD MIRROR®. ISBN 9781304729538. https://books.google.com/books?id=RL01BgAAQBAJ&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA21. 
  2. "Continual Re-enchantment: Tunde Kelani's Village Films and the Spectres of Early African Cinema". framescinemajournal.com. Archived from the original on 2020-11-01. Retrieved 2021-05-20. 
  3. "Narrow Path by Tunde Kelani". naijarules.com. Archived from the original on 2015-04-09. Retrieved 2021-05-20. 
  4. Kerr, David; Banham, Martin; Gibbs, James; Plastow, Jane; Osofisan, Femi (2011). Media and Performance. ISBN 9781847010384. https://books.google.com/books?id=dFzMC-nHqi4C&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA38. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Nelliwinne