"Green-Eyed Lady" | ||||
---|---|---|---|---|
Fáìlì:Green-Eyed Lady - Sugarloaf.jpg | ||||
Single by Sugarloaf | ||||
from the album Sugarloaf | ||||
B-side | "West of Tomorrow" | |||
Released | Oṣù kẹ́jọ ọdún 1970 | |||
Genre | Jazz fusion, psychedelic rock | |||
Length | 6:53 (album version) 5:58 (long single version) 2:58 (radio edit) 3:33 (short single version) | |||
Label | Liberty Records | |||
Songwriter(s) | Jerry Corbetta, J.C. Phillips & David Riordan[1] | |||
Sugarloaf singles chronology | ||||
|
"Green-Eyed Lady" jẹ́ orin àdákọ tó gbajúmọ̀ láti ọwọ́ Amẹ́ríkà rọọ̀kì baàdì Sugarloaf. Ó di kíkọ lọ́wọ́Jerry Corbetta, J.C. Phillips àti David Riordan,[1] Wọ́n kọ́kọ́ fi orin yìí ṣe álíbọ̀mù wọn, Sugarloaf àti jẹ́ orin àdákọ wọn. Ó lọ sókè sí ipò kẹ́ta lórí Billboard Hot 100 ní ọdún 1970 àti wí pé ó jẹ́ orin àdákọ àkọ́kọ́ RPM Magazine fún oṣù méjì.[2] Ó ṣe jẹ́ orin tó gbajúmọ̀ fún ẹgbẹ́ náà It , gẹ́gẹ́ bí ipò tí Last.fm fi sí.[3] Wọ́n ti wá lo orin náà ní Ọ̀pọ̀lọpọ̀ álíbọ̀mù.[4]