Thunderbolt: Magun | |
---|---|
Fáìlì:Thunderbolt (2001 film) poster.jpg | |
Adarí | Tunde Kelani |
Olùgbékalẹ̀ | Tunde Kelani |
Òǹkọ̀wé | Adebayo Faleti |
Àwọn òṣèré | Lanre Balogun Uche Osotule Ngozi Nwosu Bukky Ajayi |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Mainframe Films and Television Productions |
Ìnáwó | $50,000 |
Thunderbolt: Mágùn jẹ́ fíìmù ti ọdún 2001 ní Nigeria, eré tíTunde Kelani ṣe olùdarí àti ṣe. Ó dá lórí àkọlé ìwé Mágùn tíAdebayo Faleti kọ, àtipé ó ṣe àtúnṣe fún èrè ìbòjú nípasẹ̀ Fẹ́mi Káyọ̀dé . [1]