Tunde Babalola | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | England |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian / British |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Screenwriter |
Ìgbà iṣẹ́ | 1997–present |
Tunde Babalola jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì jẹ́ akọ̀tàn fún fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ti ilẹ̀ Britain.[1] Ó gbajúmọ̀ fún àwọn fíìmù bíi Last Flight to Abuja, Critical Assignment, October 1 àti Citation tí ó ti kọ,[2] àti àwọn fíìmù ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán bíi Tinsel The Bill àti In Exile. Ó kópa nínú fíìmù ọdún 2001 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Deep Freeze, àmọ́ ó sọ ọ́ di mímọ̀ pé ìyẹn kọ́ ni iṣẹ́ tí òun yàn láàyò.[3]