Uru Eke | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | 11 October 1979 Newham, East London | (ọmọ ọdún 45)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Business Information Technology, University of Greenwich |
Iṣẹ́ | Actress and film producer |
Gbajúmọ̀ fún | Her role as Obi in Ndani TV |
Notable work | Last Flight to Abuja |
Uru Eke /θj/ (tí wọ́n bí ní October 11, 1979) jẹ́ òṣèrèbìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti aṣàgbéjáde fíìmù àgbéléwò. Ó gbajúmọ̀ fún fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Remember Me".Ó kópa gẹ́gẹ́ bí i ẹ̀dá-ìtàn Obi nínú àwọn fíìmù orí èrọ-amóhùnmáwòrán lórí Ndani TV, bí i Rumour Has It. Last Flight to Abuja, àti fíìmù ẹléẹ̀kejì tó ṣàgbéjáde, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ For Old Times' Sake.[1] Òṣèrébìnrin náà tó fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ kí ó tó darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ fíìmù ṣì máa ń wá àyè láti ṣe iṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ[2].