Zack Orji | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Zachee Ama Orji 1960 (ọmọ ọdún 64–65) Libreville, Gabon |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Nigeria Nsukka |
Iṣẹ́ | Actor-Director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1991-present |
Gbajúmọ̀ fún | Role in Glamour Girls, and Blood Money. |
Olólùfẹ́ | Ngozi Orji |
Àwọn ọmọ | 3 |
Zachee Ama Orji (tí wọ́n bí ní ọdún 1960) jẹ́ òṣèrékùnrin, olùdarí, aṣagbátẹrù fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[1][2] tí ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Glamour Girls, àti Blood Money. Yàtọ̀ sí eré-ṣíṣe, Orji jẹ́ oníwàásù.[3]